Oju ewe akokan
 Wiwonu ise




Itupale si ede miran:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
नेपाली / Nepālī
Polszczyzna
Português
Romãnã
Русский
ไทย / Thai
اردو / Urdu

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

ABOJUTO

Ma Wo Ibiti A nlo

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Iwe Idanileko

Opolopo igba la ma n foju fo abala yi ninu akanse ise; Anilo lati mo ibi ti Anlo ti abafe sako kuro lori afojusun wa

Lakokan ati mo Abojuto pe o se pataki, osi ye ko wa ninu akosile bi ati fe se akanse ise. Ni bayi ti ise ti nlo, onilo lati fisi ojuse.

Abojuto se pataki bi igbese ti A n gbe. Ye akosile idanileko wo: "Abojuto."

Niran afiwe gigun keke? Bi ose nte pedali je ise, wiwo ibi ti o nlo se (Abojuto) se pataki, ti ko ba ni kuro loju ona kosi subu kuro lona. O le so pe awon to n sise akanse naa nwo sugbon ko to rara.

Gbogbo ara ni awa keke na nlo lati fi wa keke, kise oju nikan. Oju gbodo sise pelu opolo ki o le so fun ara yoku pe bayi ni ke se se. Orisirisi eniyan o n sise akanse nigbakan tabi omiran, sugbo adugbo tabi awon ti won fi owosile gbodo mo bawoni ise naa se nlosi.

Nigbati ise ti nlo bayi, ise arunisokeni lati ran adari leti pe akanse ise naa nilo abojuto, ose pataki o si gbodo see

––»«––

Abojuto Adugbo ati Iyiriwo:


Abojuto Adugbo ati Iyiriwo

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise