Oju Ewe Akoko
Gbigbaradi



Awon Eda:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
বাংলা / Baṅla
Български език
Català
Cebuano / Sugboanon
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Euskara
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Polszczyzna
Português
Română
Русский
सिन्धी / Sindhi
Af Soomaali
తెలుగు /Telugu
Tiếng Việt
Türkçe
اردو / Urdu
Èdè Yorùbá

                                        

Awon oju iwe miran

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

SE IDAMO AWUJO TI O FI OJU SUN

Awon Eniyan wo Ni Akitiyan Re Yio Gbe Fun?

Lati Owo Ojogbon Phil Bartle, PhD

ti a se eda re lati owo ADEBUNMI, Adetona Amos


Iwe Ilewo Fun Idanileko

Bi a se n je eniti o n se iwadi lori eto iba-ara-eni-gbe ati eni ti o n se agbeyewo  Amokoko ti o pegede gbodo mo nipa ohun gbogbo ti o je mo amo

Owe miran ti a maa n lo nipa eto itesiwaju fun awujo nis, "Amokokongbodo mo iru amo ti o n lo." Awujo yen ni amo re. O n gbiyanju lati mo ki o le di ohun ti o fi ese mule daada.

Lati le se eyi, o nilati mo opololpo nkan nipa awujo (ati nipa awon abuda awon awujo). O ni lati mo ohun gbogbo ti o ye nipa awon bi a ti n ko ara eni jo ni elegbe-jegbe, eto oro aje, awon ede, aworan bi adugbo re ri, awon isoro, iselu, ati awon imo ti o ro mo ile, igi, oke ati beebeelo.

Eto iwadi re ko gbodo je pe lati kan se akojopo awon koko otito kan ti ko fi ara pe ara won; O gbodo tan wo yebe-yebe ki o le wulo fun o lati ni imo lori awon abuda eto iba-ara-eni gbe po ni awujo. (See Ki ni Awujo? ati Eto Iwadi lori biba ara eni gbe).

Ro arojinle nipa bi gbogbo ohun ti o ro mo se fi ara pe ara won.

Ona kan lati bere dara dara ni lati ya aworan. Nibo ni awon eniyan n gbe? Iru awon ohun amulo ti o wulo wo ni o wa ni aarin adugbo? (fun apere opopo ona, ese kuku, omi, ile iwosan alaboode, ile iwe, eto imototo, oja ati ohun miran bee ti o wulo fun awujo).

Lehin naa, nigba ti o ba mun awon olugbe awujo lati jo se agbeyewo kan nipa bi awujo se wa gan an (awon alumoni ti won ni, awon aini won, awon anfani ti o wa, awon isoro ti o da oju ko won);o o to won si ona lati ya awora bi awujo se ri. ti o ba se okan fun ara re ni isinsinyi yio ran o lowo ni ojo iwaju nigba ti o ba nilo lati see pelu awon eniyan ni awujo.

Se awon akosile re ni ojo ninu iwe akosile re. Se akosile awon ohun ti o se awari nipa awujo: Eto bi a se n ba ara eni gbe,eto oro aje, awon ade, eto oselu, awon ohun ti a jo gbe ni aruge, awon asa, ati bi a se n se amulo awon ohun ti Eleda fi yi wa ka (ecology).

Te siwaju lati maa se agbeyewo awon ona ti awon ohun wonyi se n fi ara ro ara won.

––»«––
Ti o ba se adako ohunkohun lati ihin yi, jowo fi oriyin fun eni (tabi awon) ti o koko se agbkale re
ki o si tun pada wa fi ori re so cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2012.03.18

 Oju Ewe Akoko
Gbigbaradi