Oju ewe akokan
 Wiwonu ise




Awon Itumo:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
Polszczyzna
Português
Romãnã
Русский
ไทย / Thai
اردو / Urdu

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

IMUSE ALAKALE ISE ADUGBO

Ise Irolagbara

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Iwe Idanilleko

Titele alakale ise je sise akanse ise

Ninu abala imurasile, okeretan meji ninu awon eto lo gbodo ko sile (lati owo adari), gba ase (lati owo gbogbo adugbo). Awon ni: (1) CAP (Alakale ise adugbo) tabi Alakale ise, ati (2) Isupo akanse ise (ti o le wa tabi koma wa ninu iwe akojopo fun ise naa).

Biko ba se pe adari tabi aladugbo yi pada, a gbodo ma se itokasi won ni gbogbo igba, papajulo nigba edeaiyede, tabi ibere nipa ohnu toba kan. Agbodo ri isupo akanse ise gegebi ara alakale ise.

Ojuse re ko ni lati se ise bi ko se lati ko ara adugbo la se e.

Ri daju pe eni kookan se ise tire.Ki o si boju to ise naa.Ri daju pe ipade wa lore kore larin adari (nibiti eti ma fi akosile bi ise se nlo si han) ati ipade gbogbo adugbo. Bakan naa ri pe akosile to pe ni won se, papajulo awon eto inawo gbogbo.

Ran adari lati se akosile gbogbo inawo awon alakoso (iye wakati melo ni won lo ni ipade, alakale, imojuto, imuse se, kini osuwon si owo, awon asiko ati agbara won?). Eyi ni awon ipade larin te se pelu adari ati die larin awon ara ilu.

––»«––

Ise adigbo; Gbigbe Koto idaminu:


Ise adugbo; Gbigbe koto idaminu

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise