Awon Eda:
Akan | KOKO INU OROLati Owo Phil BartleTi a gbifo re lati owo Ade O'Dwyer, Toyin Olawale JenyoAwon wonyi ki i se itumo, sugbon won je awon akosile nipa awon ikori ti o jemo ifiagbara fun awon awujo ti owo oya won kere. A dari won si awon osise awujo, sugbon o le je ohun ti awon aseto, ajijagbara, omowe, akeko, oluwadi, osise ero- ayarabiasa, alakoso, alakoso ti o lowo ninu imukuro osi ati idagbasoke ti o ntesiwaju laarin awon awujo ti owo oya won kere ni ife si.As with most of the training material on these pages, you are invited to download these files, print them for training sessions, or to translate into local languages. Do not plagiarize. Please indicate the source. The words are grouped alphabetically. Click on the letter above that begins a word you want to see. We recommend that you also browse through all of the words. Working Bibliography, references in the literature used in the field. ––»«––Glossary, words specific to sociology. ––»«––The six core words
──»«──Ti o ba ri oro ti o nilo ijiroro nibiyi, jowo.Ti o ba se adako ohunkohun lati ihin yi, |
Oju Ewe Akoko |
Gbigbaradi |