Oju - iwe akookan




Ogbufo:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
বাংলা / Baṅla
Български език
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
Português
Română
Русский
Српски / Srpski
తెలుగు /Telugu
ไทย / Thai
Tiếng Việt
Türkçe
اردو / Urdu
Èdè Yorùbá

                                        

Oju - iwe miran:

Awon Akojopo - eko

Olutosona aaye ayelujara

Koko oro

Olubasoro

Awon iwe - ipamo ti o wulo

Isoopo ti o wulo

Eko nipa eda eniyan ati asa re

TITESIWAJU AWON ONA - ABAYO

O koja olusekoriya kan

nipase Phil Bartle, PhD

itumo nipase Toyin Jenyo


Oro Isaaju Akojopo - eko (ibudo)

Awon iwe - ipamo ti o wa ninu Titesiwaju Akojopo -eko

Ti o ba lo si Ibi ti won ti ngbe iwon ki isan lee fee si leekan sooso, isan re ko ni fee si

Ti o ba wo awon koko oro ati akori ipile ti a fenuba ni Ipin kinin leekansi gegebi ohun ti o se pataki fun o lati mo, iwo yio ri oro naa "Agbara lati tesiwaju, "( a ko ri ninu iwe - itumo), Bawo ni ohun ti a fi siibikan se le tesiwaju lati wa nibi ti a fi si?

Fun awujo , ti ilepa re je lati mu ki ilera dara si, ati afojusun re je lati ko ile - igbanse, ohun ti yio je o logun nipa titesiwaju wa ninu ibeere bi, " Bawo ni a se le ri wipe ile - igbanse wa ni mimo, fun atunse imojuto ati wa ni lilo?"

Idahun si ibeere yi wa ninu riri daju pe awujo ri bi ojuse (nipa kikopa awujo ninu ipinu sise ati isakoso ) lati ibere ise agbese.

Fun iwo, ti o ti fi ilana awujo lele fun iyipada awujo, ifokunfun awujo, ohun ti yio je o logun nipa titesiwaju wa ninu ibeere bi, " Bawo ni awujo se lee tesiwaju ni sise akoso awon itesiwaju re, sise igbelewon re, yiyan awon ayo titun, wiwa eroja titun, gbigbe igbese titun, piposi ara re igbekele?"

Awon ilepa re yato si ti awujo sugbon won nran ara won lowo. O fe ki ona - abayo re ma a tesiwaju. Idahun fun awon ibeere lori titesiwaju da lori bi o ba se gbe eto isekoriya re kale.

Ilepa re ki i se ise agbese leekan fun gbogbo igba bi i ile - igbanse, ile - iwe, ile - iwosan tabi ipese omo ero. Ilepa re je idagbasoke ti o le ma tesiwaju

Akojopo - eko yi nwo bi o se le mu ki ise re ma a tesiwaju. Ara awon idahun duro lori atunse awon isekoriya alayipo funrare; ara re duro lori idanimo ati kiko awon olusekoriya laarin awon awujo afojusun.

––»«––

Asayan ise - sise alaseyori; Ose sise


Asayan ise - sise alaseyori

Ti o ba da oro ko lati ori aaye ayelujara yii, jowo daruko (awon) onkowe
ki o si soopo pada pelu cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ase 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Igbekale ayelujara nipase Lourdes Sada
––»«––
Imudojuiwon ikehin: 2015.05.13

 Oju - iwe akookan