Oju ewe akokan
 Wiwonu ise
Awon Itumo Ede:

English

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

ITAN EKINI

Won ko lati se abojuto

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Itan Kekere

Upper Mersey ho fun ayo lori ise. Isoro nla to wa niwaju won, bi ileto kan ni abala Ilu nla naa, nibiti awon odo ti nba nkan je ati lo ogun oloro. Odabi enipe Agbegbe se akitiyan lati wa ojutu si oro naa. Michael Smith ti wa si odo won, se orisirisi ipade, atipe nibayi won ti gbe ajo kan kale lati wa ojutu si oro naa, oun to dunininu julo ni pe awon odo naa ni o n sakoso ara won, lati seto ere idaraya, lati ran ara won lowo wa ise. Oto kulu kakiri nibiti oyani lenu wa fi ebun lorisirisi kale fun won, ile ise adani kan fun won ni aso idaraya pelu oruko re lara aso idaraya naa, Ile ise molemole ran won lowo lati fun won ni ohun elo ikole idaraya won. Ogooro awon onise iranse lo dagirigi lati fi owo ran won lowo. Michael Smith ko ni akoko lati joko ri gbogbo isele naa, nitoriti oni ojuse miran ni awon adugbo miran bakanna. To ba se beni, ibani fanilatile se abojuto gbogbo eto naa pelu awon aladugbo naa. Julian Cezar je ogbontarigi alakikanju oloselu. Oun lo kakiri lati wa ibo, o n fon nu pe oun lo n mu ibudo idaraya wa si Upper Mersey, Cezar si ja adugbo na gba fun eto oselu tire. Ko si gba awon ara adugbo naa laye lati so pe "awa la se e." Michael Smith nilo lati sora gidigidi fun Cezar nitori o le je Oka oloro ninu. Ni kolofin ni Michael nfi awon ore re oniroyin ni ile ise iroyin tu asiri Cezar pe oun ko lo se Ile odo, sugbon awon aladugbo funra won lo se eto re. Ti oba se pe Michael ati awon ara Upper Mersey ti bojuto gbogbo re lapapo ni, iru oro Cezar ko ba ti wa ye rara.

Akiyesi: Awon itan yi je isele to waye. Awon oruko eniyan ati ilu ni ayi pada nitori ako ni oruko enikeni lokan rara.

––»«––

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise