Awon Itumo:
Oju ewe miran:
|
WIWONU ISE
Adugbo Mura
Itupale lati owo Oladipupo Abayomi
Oro Isaaju fun eko
Awon akosile to wa ninu Igbese Eko
Olorun
ole ran eniti ko ba se igbese kankan lowo. Sophocles
Leyin
igbati o ba setan ti o si se awon eto toye larin adugbo, igbese se wa bere
Iwo,
arunisoke, ti se tan (ani mimu adugbo setan). Bayi asiko ti wa to fun awon eniyan
lati ma se igbese.
Gbogbo
aladugbo ti se abala eto kan tabi keji, wonti mo adarai, se alakale igbese gbogbo,
yan akanse ise kan, ati eto lati se e. Akoko fun ise lati bere.
Fun
apere, jekaso pe ipinu won ni lati gbe salanga. Gbe alakale ise yewo; gba awon ohun
elo, kgbigbe bere. Awon ibikookan wa ti iwo, arunisoke ti ni ise lati se. Mase se
eto, bojuto tabi gbe salanga.
Oju
sere ni lati ko won ni ise owo (se imo yato awon adari ni gbati ise adugbo ban lo
lowo), ridajupe ise naa ri abojuto, ki ekunrere ohun gbogbo si wa ni ipese (papajulo
iwe ipin owo) osigbodo je ki won mo pe ise idagbasoke adugbo won ni won nse.
Eko
yi so fun o awon ojuse re nigbati ise audgbo ba nlo.Oko le dari igbese won; ranwon
lowo lase ise won ni. Gbe oriyin fun won ni gbangba.
Se
iranwo lati mo iru eko wo ni won nilo, imo ita gbangba, ise dede tako tabo, ifojuhan
sode ati akanse ise to yege.
––»«––
Won da ohun kan tabi ekeji; Mu awon elo wa:
© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle lati owo Lourdes Sada
––»«––Atunko: 2010.10.13
|