Oju ewe akokan
 Wiwonu ise
Awon Itumo Ede:

English

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

ITAN KEJI

Won setan lati je alaisotito

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Itan Kekere

Eloise mo daju saka pe awon alakoso ise akanse adugboje olotito. Kilose iyato, botiwu kori, nipe awon kan ngbe sumomi pe won ko owo je ati pe awon iwa aisotito pe owo ilu ni won nda si apo ara won. Lakotan, Eloise lo ba alabojuto re, Andrea, lati be fun imoran ati itoni. Andrea ni enikeni o mo ladugbo naa, nigba to si be wo ko je ki enikeni da mo, osi teti si gbogbo sun mominaa. Ni gbati o pada de ibu joko re, Andrea pe Eloise fun iforo jewo. “Oda mi loju pe gbogbo oro to so nipa awon alakoso je otito,” beni Andrea wi. “Sugbon awon olugbe adugbo naa ko ri be e.”Mo tun se akiyesi awon nkan wonyi, bi pe awon alakoso ko fo ju bi won se n se han so de si gbogbo adugbo; won mu gbogbo adugbo“saba le lori.” Eloise pada si abule o si pe ipade awon alakoso ni wara nse sa. O se ikilo fun won pe oun ma koro oju si won, osi se be. Isoro akoko nipe won ko ni aworan rere niwaju awon, eyi to je pe ofarahan nipa aile jeki gbogbo ohun ti won n se han si gbogbo eniyan. “Ki se ki won so ododo nikan , bi ko se pe ki won ri won pe won nso,” eyi lo so fun won. Won si jo pawopo lati se ipade pelu gbogbo gbo ni ose mejimeji nibi ti won ti ma ma so ise irju won, itesiwaju, bi owo se wole ati bo se jade, ati dida hun oniruru ibere lati odo awon aladugbo. Ni ibere ipade ita gban gba opolopo lo ko pa, sugbon nigbati ose die opolopo fa seyin, eyi tesiwaju titi ofi di pe iwonba awon to fe mo bi gbogbo akoso se nlo loku ti o nwa si ipade naa. Bayi ni Eloise ati alakoso se se gba isakoso nipa sise afihan sode.

Akiyesi: Awon itan yi je isele to waye. Awon oruko eniyan ati ilu ni ayi pada nitori ako ni oruko enikeni lokan rara.

––»«––

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise