Oju ewe akokan
 Wiwonu ise




Awon Itumo Ede:

English

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

ITAN KETA

O se Ajoyo

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Itan Kekere

Inu Elvis dun. Ise akanse re akoko, o gba won niyanju, ati dari sugbon awon aladugbo lo se ise naa, won si se pari re ni. Enu eyi to ku na ni ajoyo ikadi ise akanse. O ti bere si se ajoyo ojo naa koto di ojo ajoyo gan. Kini ise wa wa fun? Kofi to awon Eekan ninu ijoba leti tabi ko se iwe ilewo nipa eto naa. O ti gba gbe awonu to ranwon lowo lnipa owo lati okere. Ko si tun niran awon ore re larin awon oniroyin mo, owo alejo won ki won le ko oro sinu iwe iroyin lati fi ipa ti awon olugbe adugbo ko nipa ise naa, beni kosi seto owo oko fun won.Ko so fun awon alakoso lati ra oti elerindodo fun awon ti oba wa si ajoyo.Beni ko ranwon leti lati so fun Oludari ile iwe lati fi awon akeko sile ki won le korin fun awon alejo ni ajoyo. Won ko gba ero agbohun si afefe. Won ko so fun awon alajo ta, ati amuludun lati da awon eniyan lara ya.Paba nbari ni pe ko so fun adari awon alakoso lati mura oro lori bi won oti se ise akanse tuntun. Ah, sibesibe Elvis se ajoyo. Irufe ajojo bayi je adanu gba a.

Akiyesi: Awon itan yi je isele to waye. Awon oruko eniyan ati ilu ni ayi pada nitori ako ni oruko enikeni lokan rara.

––»«––

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise