Oju Ewe Ibere
 Gbaradi




Awon Eda:

'العربية / al-ʿarabīyah
বাংলা / Baṅla
Bahasa Indonesia
Български език
Català
Cebuano / Sugboanon
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Euskara
فارسی / Fārsī
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Português
ਪੰਜਾਬੀ / Pañjābī
Română
Русский
Af Soomaali
తెలుగు /Telugu
ไทย / Thai
Tiếng Việt
Türkçe
اردو / Urdu
Èdè Yorùbá

                                        

Awon oju iwe miran

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

AWON ALUMONI TI O WA NI ODE

Sise amunlopo awon alumoni ti inu ile ati ti ode

Lati Owo Ojogbon Phil Bartle, PhD

Ti a gbifo re lati owo o Adebunmi Adetona Amos


Iwe Ilewo fun Awon Akeko

Iranlowo melo ni a le rigba lati ode awujo ki o to di pe awujo yen  eyi ti o ngbojule iranlowo lati ode, ki o si ti ipa bee so igbojule ara-eni nu?

Gegebi olusekoriya, o o se awari pe o nira lati ridaju pe awon alumoni ti a ri se amulo lati ode se dogba-ndogba pulu awon ti o wa lati inu ile.

Iwo ati awon olori ni awujo yio wa labe iti-ni-lo-gbon-gbon ti o po jojo lati se amulo awon alumoni ti o wa lode awujo.

Awon Ajo ti o n rani-lowo nipa fifi-fun-ni fe fi sile, beeni awon eniyan ni awujo pelu fe gba.

Sugbon, iwo mo pe titewo gba iralowo alumoni lati ode yio tubo je ki a maa se igbarale awon ara ita ihuwasi ki sa maa gbojule iranlowo lati odo awon eniyan yio si mu idinku ba ona ati totan ati igbarale ara eni.

Sibe awon ona wa ti a fi le se amulo ni ona ti o dara ti awujo si le ni okun si nigba ti a ba se amulo awon alumoni lati ode gege bi a ti se apejuwe re ninu itan Monmodu ati okun. (Wo Siso Awon Itan).

Ti o ba le ro awon ti o n rani-lowo nipa fifi-fun-ni lati gbe inawo fun idanileko, ise akoso fun idanileko, ati lati ran awujo loeo lati se akojopo alumoni ohun elo ikole, o o le ran ona ati totan ati igbara le ara-eni lowo.

Ti Ojise Nla naa, ike ati ola ki o maa baa, ba kan fi onje nikan fun onibaara na, se ni iba kan dabi enti o n fun ni idanilleko lati tesiwaju ninu ise agbe sise; sugbon nipa fifun un ni imoran ati owo, o ran lowo lati di eni ti o to tan.

Awon oju ewe wonyi ni o ma n ranilowo lati ri ona ati se amulo awon alumoni ti o wa lode, gege bii Awon imoran,ti o n toni ni sise agbekale awon imoran ti o munadoko.

Gege bii awon ohun elo ti o lagbara ti o ku (fun apere ina), a le se asilo awon ogbon amulo wonyi, ati pe eyi yio si nipa lori i osi nigba ti o ba pe.

E lo won daradara, ati fun ete ti o dara.

––»«––
Ti o ba se adako ohunkohun lati ihin yi, jowo fi oriyin fun eni (tabi awon) ti o koko se agbkale re
ki o si tun pada wa fi ori re so cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2012.03.18

 Oju Ewe Akoko
Gbigbaradi