GBIGBARADI
Atona fun oluse koriya
Nipase Phil Bartle, Ojogbon
Ti a gbifo re lati owo o Adebunmi Adetona Amos
Oro akoso fun Ipele
Awon iwe ti a fi kun eleyi Gbigbaradi Ipele ipele
Mimu ara re sile gege bii oluse koriya fun adugbo
O
nilo lati gbaradi ki o to le se aseyege lori ojuse riranrenilowo ni awujo
O
gbodo da o loju, o si gbodo ni oye lori awon
ete;
o gbodo mo nipa adugbo
ti o fi oju sun;
o gbod ni imo
ti a nilo;
agbekale re gbodo ye o yeke yeke awon
ero nipa
rirunisoke.
Ohun
agbese akoko ni lati bere iwe atigbadegba.
Iwe
ajako awon omo ile-iwe ti owo ko won ti dara.
O
le wu o lati lati lo iwe ajako merin ki o si pe akole okookan ninu won ni: (1) Awon
ete ati awon ero; (2) Adugbo ti a fi ojusun; (3) Awon ogbon irunisoke, ati (4) Iwe
Akosile Awon Ohun ti Se Ni Ojoojumo.
Iru
ona eyikeyi ti o wu ki a gba lati murasile, o se pataki ki a tete bere si se akosile
bayi.
Se
akosile aropo oro pelu eniti yoo kaa ni okan re.
Ipele
yi ni o nso fun o nipa awon ohun ti o nilo lati gbaradi. Sugbon mase lero wipe o
le se imurasile tan ni 'eekan gban an'
Awa
gege bii oluse koriya n ko eko lojoojumo siwaju ati siwaju si nipa awon ohun ti a
ti menuba ni ori yii.
O
je ohun ti ko ni ipari, ati pe a o ni ijakule ti a ba gba ero pe a ti mo ohun gbogbo
ti a nilo lati mo laaye.
––»«––
Ipele Ikoni Kan:
Ti o ba se adako ohun kan lati oju ewe yi, jowo gboriyin fun eniti (tabi awon ti) wo koo ki o si wa tun pada da ori re si cec.vcn.bc.ca/cmp/
Following the path of least resistance makes all rivers and some men crooked
© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle lati owo Lourdes Sada
––»«––Atunko: 2015.01.08
|