Tweet Awon Itumo Ede:
'العربية / al-ʿarabīyah |
AWON AINI IMOKini ajo CIC ma wa jadelati owo Phil Bartle, OmoweItupale lati owo Oladipupo AbayomiIwe IdalekoKi awon adari to sakiyesi irufe aini fun idanileko loti nilo lati ri awon aini naaBoti wule jepe o ko gbodo pase fun awon aladugbo tabi adari nipa idaleko, o gbodo setan lati kun won lowo nigbakugba ti won ba se awari idanileko to dara fun won. (Wo Seto Idanileko nipa mimu gun rege). Awon won yi le wulo fun akori idaleko.
O le ma le danileko ni gbogbo awon akori yi, onilo lati wa awon to le ran o lowo lati se idanileko lori won. ––»«––Idaleko
lori Isakoso adugbo; Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o |
Oju ewe akokan |
Wiwonu ise |