Oju - iwe akookan
Ogbufo:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Български език
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Euskara
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
Igbo
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
한국어 / hangugeo
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Português
Română
Русский
Српски / Srpski
>తెలుగు /Telugu
ไทย / Thai
Türkçe
اردو / Urdu
Èdè Yorùbá

                                        

Oju - iwe miran:

Akojopo - eko

Olutosona aaye ayelujara

Koko Oro

Olubasoro

Awon iwe - ipamo ti o wulo

Isoopo ti o wulo

Eko nipa eda eniyan ati asa re

BIBERE

Igbaradi fun awujo lati gbe Igbese

nipase Phil Bartle, PhD

itumo nipase Toyin jenyo


Oro Isaaju Akojopo - eko (Ibudo)

Awon iwe - ipamo ti o wa ninu Bibere Akojopo - eko

Igbese re akoko ki awujo to gbe igbese

Ninu akojopo - eko isaaju, a ri die ninu awon nkan ti a nilo (gegebi olusekoriya) lati se ati lati ko fun igbaradi. Ninu akojopo - eko yi i, a o ka nipa bibere fun ara re.

O ko le mu ki awujo gbe igbese lai ti gbaradi fun won fun iru igbese bee. Bi ibere re ba se ja fafa si bee ni igbaradi awujo yio se ja fafa si.

Fun awon olusekoriya kan, bi "ota" tabi "alatako" ni won se ri awon alase ati wipe won ri bi ise lati ko awon awujo alaini jo lati tako awon " aninilara" yi i.

O le je ona ti o to ni igba miran, ati wipe ni opo igba ni a ma nri gegebi" ikopa awon ilu" dipo "ikopa awujo."

Ilana inu akojopo - eko yi i ( ti o je jade ni pato ni Afirika) ri mimu awon alase si egbe gegebi ohun ti o sese ki o mu ki eto orile - ede ati eto lati mu osi kuro ma lo deedee, ki o si gbe e ro.

Lehin afikun sise - akiyesi laarin awon alase, ati gbigba ase ti o se pataki ki o to le se ise re, ohun ti o kan ni lati fikun sise - akiyesi laarin awujo afojusun tabi awon awujo ti a fe se koriya fun ati fi okun fun.

Fifikun sise - akiyesi laarin awon alase nipato tumo si (1) sise alaye ilepa ati (2) ilana, ati (3) fifun ni idaniloju pe won yio je anfani ninu aseyori re.

Ranti wipe iwo yio ri atako si ayipada awujo, ati wipe ni opolopo igba awon ti yio je anfani julo ma nwa lara awon ti a fojusun ni awujo.

Lehin ti o ba gba ase ti o nilo lati bere ise re awujo gbodo gbaradi(a ti fikun sise - akiyesi, isokan ti dagba si, alaye ti se deedee, a ti yan igbese ti o se pataki - julo).

Fifikun sise - akiyesi laarin awon awujo afojusun re tumo si sise alaye ilepa ati awon ilana re, o tun tumo si gbigbe ese ti o ni anfani lati se idiwo fun fifikun ireti ti ko le wa si imuse.

Riri daju wipe alaye ati itumo se deedee ni yio je o logun julo.

Akojopo - eko yi i fi han wa bi a se lee bere.

––»«––
Ti o ba da oro ko lati ori aaye ayelujara yi i, jowo daruko (awon) onkowe
ki o si soo po pada pelu cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ase 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Igbekale ayelujara nipase Lourdes Sada
––»«––
Imudojuiwon kehin: 2015.02.16

 Oju - ewe akookan