Oju Iwe Kini

Bibeere






Ogbufo

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Български език
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Euskara
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
Igbo
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
한국어 / hangugeo
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Português
Română
Русский
Српски / Srpski
>తెలుగు /Telugu
ไทย / Thai
Türkçe
اردو / Urdu

                                        

Awon Oju Iwe miran:

Modulu

Aworan Aaye

Koko

Olubasoro

Awon Iwe Ase ti o Wulo

Ijapo ti O wulo

Eko nipa eda eniyan ati asa re

PIPE AWUJO NIJA

Itako n fun ni L'agbara

nipa Phil Bartle, PhD

itumo nipase OLUTUNMBI, Tobi


Iwe Idanileko

Bi o ti le je wipe o fe ki awujo ni agbara, o ko gbodo se alaise itara lati gba n kan ti o jo eyi ti o se pataki julo ninu ilepa awon ara awujo yi

Itako a ma fun ni l'agbara ;isan apa re a ma l'agbara ti o ba n se titari soke

Ti isan re ko ba do ju ko itako, won yio di a lai lagbra. Ti o ba se n kan pupo ju fun awujo, yio di a lai lagbara.

Aba akoko ti o se pataki ti awon ara awujo ba mu wa le ma je eyi ti won ro daada, ti o ba se itako re, won le lo farabale tun igbese won ro

Je ki a gbe apeere kan wo. Boya awon ara awujo so wipe ilepa awon ti o se pataki julo ni lati ko ile iwosan

"Ko buru, iwo a da won lohun wipe," Sugbon ki ni ero ti o wa ni idi yiyan ilepa yi?" se awujo yi ni agbara lati ko ati lati bojuto ile-iwosan?" " Ki ni awon isoro ti ile-iwosan yi yio yanju?" Ati ki n awon isoro ti yi o da sile

Fun won l'agbara nipa jije ki won gbeja o hun ti won yan

Ti o ba je yo wipe awon ara awujo yi fe ile-iwosan ni tori wipe awujo orogun kan ni isale ona won ni okan, pe o hun ti o n se iwuri fun won ni igberaga, igba na ni ki o wa se alaye fun won wipe

"E ranti wipe eyin ni e ni o hun elo ti yi o lo si nu kiko ile yi; se o da yin loju wipe n kan ti e fe na owo yi n le lori re? iwo yi o so

Boya o je yo wipe awon ikoko ti wa n ku, ati wipe eyi ni akoko bere nkan ti o kan won

Anfani wa ni eyi je fun o lati fi koko ti o se pataki ninu PHC,idena dara ju iwosan lo

Awon ikoko n ku ni pato nitori igbe gburuu ti o sele nipa arun ti o n tan kale nipa omi Omi.

Ile-iwosan le ran won lowo lati wo ailera san, sugbon o se oninure, din wo ati wipe eewu re kere lati din awon arun ti tan ka nipa omi ku nipase kiko nkan meta papo:(1)idanileko imototo ti yio yori si ayipada iwuwasi, (2)ipese omi ti o se mu ati(3)imototo ti o muna doko ti o n toju egbin eniyan kuro ni ibi omi mimu. Idena dipo iwosan

Ni pa ipenija lati se itupale awon isoro ati lati se awari fun ojutu ti o wulo ati ti o seese, awujo le dahun nipa titun se ayewo awon isoro ti o se pataki julo ati lati tun se asoye awon ilepa ti o se pataki julo

.Ma se gba ilepa akoko ti won yan lai se itara

––»«––

© Asekiko 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Oniru Ayelujara nipa Lourdes Sada
––»«––
imudoju iwonkehin: 2015.02.16

 Oju iwe kini

 Sise Ibeere