Oju ewe akokan
 Wiwonu ise




Awon itumo:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
नेपाली / Nepālī
Hindi
Polszczyzna
Português
Romãnã
Русский
ไทย / Thai
اردو / Urdu

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

AJOYO

Ipari ati Ibere Ohun tuntun

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Iwe Idanileko

Okan pataki ni awejewemu je lara ojuse re, kii sii se asiko igbalude

Eto ati mimuwa si ojuse ajoyo adugbo je ise to se takuntakun, osi se pataki lara iruni soke.

Ti oko ba mo eyidaju; awon akeko ati opolopo osise, asiko igbafe to yato si igba ikeko ni ajoyo je. Fun iwo, arunisoke, oje okan ninu ise alakale re.

Be lofarahan kedere fun ajoyo (fun apere ikadi ise adugbo), ogbodo se igbelaruge awon ajoyo gbogbo yoku nipase igbekale bi: Ikowojo, fifi ipile ile lele, wiwo ifase sile, pipari abala kan (awon ogiri, orule, kikun) ati awon eka to tun se pataki.

Ilu lilu, ijo, ere, yiyan, ebun fifihan, ati awon oniruru ere igbafe loye ko wa ni inu ajoyo naa. Fiwe pe awon elere ibile to wa ni tosi ati ni ile iwe kaakiri lati kopa. Ri daju pe awon eekan wa si ibi ipade ita gbangba fun oriyin (sugbon ki se fun ipolongo oselu), ati ki o si pe awon oniroyin bakan naa.

Kinidi?

Ajoyo a ma muni je mi mo si ni awujo, fidimule ati loorin si ninu ise idagbasoke, ki si se ise lasan.

Asiko yi je igbati ama n polongo, farahan, ati ti a ma n mu ise adugbo wa di okan pataki ni gbogbo agbegbe.

Pelu awon adari, se eto ati atunto daradara. Ma se gbogbo eto fun awon adari.

Gba won niyanju,gbe oriyin funwon ati funwon ni imoran, -lati wa ni ojuse. Wo "Ayoyo."

Igbadun.

––»«––

Ipari Ise; Aseye & Ajoyo:


Lilu ilu ni ibi Ajoyo

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise