Awon Itumo Ede:
Oju iwe miran:
|
Onati ale gba ri awon oro to bere pelu leta:
MASE ITUPALE ONA SI AWON EDE. FIWON SILE NI BI WON TI WA.
KOKO ORO NINU EKO "SISE ETO ADUGBO"
Itupale lati owo OLADIPUPO ABAYOMI FOLA
Ajoyo:
Akoko ajoyo ma n je asiko ti idunnu farahan papajulo ti isele to yi igbesi aye pada jojo. (Se ayewo:
Iyipada igbe aye eda). Ajoyo je ipade gbangba
Fun arunisoke, ajoyo ipari ise akanse adugbo se pataki fun irolagbara adugbo, nibiti gbogbo eniyan ti se ise ifara eni jin to si yori si rere. Otun je anfani lati bere ise akanse tuntun.
Yewo Irunisoke
Ilopo. Yewo
Ajoyo.
Monitoring:
Monitoring is the regular observation, recording, analysing and reporting of activities and the results of those activities, in a project or similar activity. (See
Monitoring).
Afihan Abojuto:
Amin didara ati pipo to fun oduwon tabi agbeyewo aseyori gbogbo, tabi giga aseyori awon ise akanse, afojusun ati abajade gbogbo.
Awon afojusun naa gbodo se yiiri wo. Wo
Oduwon Agbara fun afihan abayori irufe irusoke adugbo, ani irolagbara.
Aye ikeko:
"Aye ikeko" le je ojo kan tabi ju belo. Oyato si ijiroro (eyi tumo si kikopo tabi siso oro po). Aye ikeko wafun eko kiko, osi gbodo ni alakale abayori re.
Ninu ikeko, ise je eko, ati abajade gbodo je marun ninu awon idi ti afi se
idanileko ti afihan ninu fanranyi . Yewo "Imurasile fun Eko kiko."
──»«──
If you find a word that needs discussing here, please
write.
This site is hosted by the Vancouver Community Network
(VCN)
Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o ki osi dari wa
www.cec.vcn.bc.ca
© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle lati owo Lourdes Sada
──»«──Atunko:
2012.10.09
|