Oju ewe akokan
 Wiwonu ise




Awon Itumo Ede:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
नेपाली / Nepālī
Polszczyzna
Português
Romãnã
Русский
اردو / Urdu

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

IMUJADE AINI ADUGBO

Kogbodo je Imujade Aini lati Odo Lajolajo

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Iwe Idanileko

Ni kete ti ise akanse bati bere, awon adari mo
oun ti se alaini

Nigbati ise akanse ba si nlo, adugbo ati awon adari won a bere si ri pe awon nilo oye tuntun.

Awon miran le je ti ise owo, bi ise ona, amo ile, aso okun ina, ati awon miran to wulo fun ise akanse won. Awon miran leje ti isuna owo, eto ati isakoso, Piari ija, fifi owo pamo, ibanisoro to ja gara, ati bebe lo.

Idanileko wa ni orisirisi to nfi imo han lati ori iriri si eyiti koni iriri, idaleko ti afi owo se (bii ise owo), nipa idanilekoti o gbekale, lati tun ran akopa lo si idanileko ti adani tabi ti ile iwe ijoba.

Ju gbogbo relo, se atenumo ise owo ti ose ko lati inu adugbo. Awon Agba ati Oniriri onise owo gbodo ma fi ise naa han awon oso weere ti won se n sise.

Ni bi to ba ye ki a gba onise owo, se akitiyan lati gba ninu adugbo naa toba sese, se eto pelueni ti onise owo ti e gba ati tun daleko awon odo kunrin and obinrin.Ri daju pe adari se akosile gbogbo irufe idaleko naa.

Nibiti irufe idanileko be obati se se, se eto fun idanileko miran. O gbodo ni eto isuna, ona ibiti owo ti le wole, latile san owo idanileko.

Bi irufe idanileko ba jeyo fun ojo iwaju lati odo adari, je won se akosile gbogbo ohun ti won nilo kosi wa lara alakale ise adugbo. Yewo: Imura fun Idanileko.

O le ran awon eniyan lo si iadileko ile iwe ijoba bi owo ba wa ti ase awon ajo ti ogbe eto naa kale ba fi aye gba irufe idaleko be.

Ojuse re ni lati ri pe ogba ase lori gbogbo eto idanileko lati odo awon aladugbo, je ki o ba aini awon aladugbo naa mu. Ri daju pe yiyan akopa ati akori ise akanse lati odo awon aladugbo. Eyi ma ranwa lowo safun fiura ojusaaju.

Irufe idaleko ti koba je, nigbati aknse ise nlo, ri daju pe yiyan akopa ati akori, wulo fun adugbo, ase si wa lati se ninu adugbo naa, se abojuto ati akosile, ko si jeyo ninu akosile itesiwaju.

––»«––

Ipade Adugbo; Mimo awon Aini:


Ipade Adugbo; Mimo awon Aini

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise