Oju ewe akokan
 Wiwonu ise
Awon itumo:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
नेपाली / Nepālī
Polszczyzna
Português
Romãnã
Русский
ไทย / Thai
اردو / Urdu

                                        

Oju ewe miran:

Ipele, Ipele

Aworan ibe

Awon oro ti o se koko

Kan si

Awon iwe ti o wulo

Awon asopo ti o wulo

IBASORO LARIN ADARI ATI GBOGBO

Imu ise se to han si ode

lati owo Phil Bartle, Omowe

Itupale lati owo Oladipupo Abayomi


Iwe Idanileko

Imuwa sojuse gbodo je oro gbangba; ti awon aladugbo gbodo mo ki lo n sele

Ojuse re ni lati fi oun gbogbo han sode, kikoni, kise apeko, atipe ogbodo jeki awon aladugbo wa ninu awon to n se akoso eto, be naa logbodo gba adari niyanju lati se si awon ara adugbo to wa.

Lati ripe ibasoropo to danmoran wa larin adari ati adogbo re, to si nse be nigbogbo igba, nipase: ipade,akosile,ati abewo.

Ipade adugbo je onakan gbogi ti ibasepo to loorin mafi wa larin adari ati aladugbo lapapo. (Ale se ajoyo ninu irufe awon ipade miran). Ninu ipade o le so fun adari kan ko kown bi ose ma n se gegebi arunisoke.

Won nilo lati mu dagbasoke bi ati le soro lawujo, pipe oro so, iwasu, tabi ifo ede latile mu akopa tele won ninu eko. Oro gbigbo pin si abala meji( 'siso ati gbigbo'), eyi ale mu ifojuhan sode, isakoso ati ibasepo to jagaara wa.

Akosile se pataki. Won gbodo le ko iwe tabi ede dara, ti won ole so bi oro ninu ipade adugbo won. Je ki aon aladugbo dasi.

Se ibewo, nibiti awon aladugbo ba ti n rin pelu adari won lori ise akanse tun ma n je iwuri ati ifoju ahn sode ohun gbogbo.

Iwe ilewo tun ma n ran ibasoro lowo, sugbon kodara to lati lo oohun nik kan.O le se afojusun lilo re lati fi pe ero jo, tabi lati fi se akosile bi gbogbo ise akanse na ti se lo.

Akosile eto inawo, je ona ifoju han sode nipa lile bi owo se wole ati bi o se di nina momara ogiri ibi ti ise akanse naa ti nlo.

Ohun to tun se pataki fun o, bi arunisoke, ni lati se atenumo sise akoso daradara, jije olotito,ifojuhan sode, nipa ibaosro to ja garaga larin adari ati aladugbo lapapo.

ona ti o gba ko bi ase n koni ni orisirisi ona oludari yoo se apejuwe bi ose le gba won niyanju ati ko adari ati oludari adugbo adugbo lati le mu won lo bakan naa.

––»«––

Kiko adugbo jo:


Kiko adugbo joCommunity Gathering

Ti o ba da iwe yi ko, jowo se afihan awon ti won ko o
ki osi dari wa cec.vcn.bc.ca/cmp/

© Ofin adako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
lati owo Lourdes Sada
––»«––
Atunko: 2010.10.13

 Oju ewe akokan

 Wiwonu ise