Oju - iwe akookan
Titesiwaju awon ona - abayo




Ogbufo:

'العربية / al-ʿarabīyah
Bahasa Indonesia
বাংলা / Baṅla
Български език
Català
中文 / Zhōngwén
Deutsch
English
Español
Filipino/Tagalog
Français
Galego
Ελληνικά / Elliniká
हिन्दी / hindī
Italiano
日本語 / Nihongo
Kiswahili
한국어 / Hangugeo
Português
Română
Русский
Српски / Srpski
తెలుగు /Telugu
ไทย / Thai
Tiếng Việt
Türkçe
اردو / Urdu
Èdè Yorùbá

                                        

Ona kika miran:

Oro

Oju - iwe miran:

Awon Akojopo - eko

Olutosona aaye ayelujara

Koko oro

Olubasoro

Awon iwe - ipamo ti o wulo

Isoopo ti o wulo

Eko nipa eda eniyan ati asa re

TITE AWON IDAGBASOKE ISEKORIYA ALAYIPO SIWAJU

Ise agbese kan je ibere ise ni awujo

nipase Phil Bartle, PhD

itumo nipase Toyin Jenyo


Iwe Idanileko

Ona abayo kookan, isekoriya alayipo kookan, agbese awujo kookan, sojuuse won si ifokun fun awujo; won gbodo je ohun ti a le tunse ninu ilana won

Ni ibeere, ise re - ona abayo re - ni won ka si riru ilana awujo soke. Awon akitiyan ti o telera, ( agbeyewo, fifikun sise - akiyesi, iseto isokan, igbero ati sise eto fun igbese, ati ayewo leekansi), ru ifokunfun awoju soke ati ominira ti o po sii,

"Alayipo " lee da bi oro ti o le sinilona nibiyi. Nitooto ni ipari o tun ma pada lati beere ni ibeere leekansi, sugbon o ma je eniyan oto ati awujo oto. Owe Buddhist atijo so wipe, "Okunrin kan naa ko lee da odo kan naa koja leemeji, "( ati eniyan ati odo ti yii pada; won si nyipada si i),

Bi o ti wu ki o ri, o ma fe lati ma a tun awon ona - abayo ti o se pataki se ati lati ru awon ilana awujo ti o se pataki soke. Gegebi ese keke olobiripo se ma yipo lere lera, ti apa kookan npade apa keji niwaju bi won se yipo lo,

Nibayi, o gbodo fi ilokuro re ti ko le yipada si okan lati igba ti o ti bere ise re. Ti awujo ko ba le e dagba soke laisi o ni ibe, nigba naa awujo ti gbarale o. Ota re si ni gbigbe ara le o je.

Nigba ti o ba ntun alayipo se, nitori naa o ni lati fi okan si ifehinti re, ki alayipo yi i lee ma tesiwaju laisi o nibe. Ti a ba ropo re,awon akosile re ninu iwe akosile, pipada si awon Ipin 1, ye ki o je ipile fun iwe idagbere fun eni ti o nropo re, Ti abewe re ko ba ropo re, o gbodo wa, ki o si mu dagba eroja ti o se lo fun isekoriya lati inu awujo

––»«––

© Ase 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Igbekale ayelujara nipase Lourdes Sada
––»«––
Imudojuiwon ikehin: 2015.03.28

 Oju - iwe akookan

 Titesiwaju awon ona - abayo