Ogbufo:
|
lsoopo pelu awon oro ti o bere pelu:
KOKO ORO FUN "TITESIWAJU AWON ONA - ABAYO" AKOJOPO - EKO
itumo nipase Toyin Jenyo
.
Agbara lati tesiwaju:
Oro " agbara lati tesiwaju" je koko ninu eto iranlowo fun idagbasoke. ( a ko lee ri oro yii ninu opolopo iwe itumo - oro). O tumo si "agbara" ohun kan lati "tesiwaju" ( te siwaju sii) lehin ti a ba mu atileyin ara - ita kuro. Fun awon awujo ti o seto omi ero, atunse, fifo ati lilo ero ifa - omi lehin ti a ti ko tan, ni awon ohun ti a fe
Fun Olugbowosile lati ita, itesiwaju awon ise - agbese tabi aseyori ise - agbese lehin ti olugbowosile ba ti fiwon sile. Fun iwo ti o je olusekoriya, itesiwaju awujo, ifokunfun eto awujo lehin ti o ba ti fiwon sile. Fun olumojuto ayika ati awon ohun abemi, itesiwaju nilo ki ayika lee se atileyin fun asayan ise - sise, ti of i je wipe awon ohun elo ti a ko le sodotun ko ni tan.
––»«––
Ti o ba ri oro ti o nilo ijiroro nibiyi, jowo ko o.
Ti o ba da oro ko lati ori aaye ayelujara yii, jowo daruko (awon) onkowe ki o si soopo pada pelu www.cec.vcn.bc.ca
Aaye ayelujara yi ni a gbani alejo nipase awon Awujo Ayelujara Vancouver (VCN)
© Ase 1967, 1987, 2007 Phil Bartle Igbekale ayelujara nipase Lourdes Sada
––»«––Imudojuiwon ikehin:
2015.5.28
|