Awon Eda:
|
lsoopo pelu awon oro ti o bere pelu:
Koko oro ti o bere pelu I
Ti a gbifo re lati owo o Ade O'Dwyer, Toyin Jenyo
IBARAMU - ASA (Acculturation)
Awon oro “ Ibaramu – Asa” tunmo si awon ona ti a fi nko asa titun, ni iyato si
Iloye – Asa (enculturation) ( kiko awon asa ibi ibi eni.. Awon onimoijinle awujo kan gbe itumo mejeeji si ara won)
Ni opo igba eyi tumo si lilo lati gbe awujo ti
asa won yato, sugbon o tun je ara ifikora ti a nilo lati faramo ayipada (i.e idagbasoke) ni awujo wa.
Ise re gegebi olusekoriya yori si ayipada
(Idagbasoke) ninu awujo. Awon eniyan awujo yi gbodo ni “ibaramu asa” (ifikora) si awujo ti o sese ni ayipada.
Wo awon ijiroro lori
Ibakegbe leekansi.
IDAGBASOKE (DEVELOPMENT)
ILOYE – ASA (ENCULTURATION)
––»«––
Ti o ba ri oro ti o nilo ijiroro nibiyi, jowo.
Aaye ayelujara yi ni a gbani alejo nipase awon Awujo Ayelujara Vancouver (VCN)
© Ofin odako
1967, 1987, 2007 Phil Bartle Lati wo Lourdes Sada
──»«──Atunko:
2015.09.24
|