Home Page
 Yoruba Key Words


Awon Eda:

Akan
العربية /   أ
العربية /   ع
Bahasa Indonesia
Български език
Català
Deutsch
Ελληνικά
English
Español
Euskara
Ewe
Filipino/Tagalog
Français
Galego
हिन्दी  / ऍ
हिन्दी  / अ
हिन्दी  / ए
हिन्दी  / आ
Italiano
日本語
Kiswahili
بهاس ملايو / Bahasa Melayu
Nederlands
Polski / a
Polski / ą
Português
Română
Русский
Srpski
Af Soomaali
Tiếng Việt
Türkçe
اردو /  ﺎ
اردو /  أ
Yoruba

                          

Oju - iwe miran:
Awon Akojopo - eko

iseoroawujo:
Eko nipa eda eniyan ati asa re
Lecture Notes
Ijiroro

Utilities:
Awon Akojopo - eko
Olubasoro
Awon iwe - ipamo ti o wulo
Isoopo ti o wulo


lsoopo pelu awon oro ti o bere pelu:

  A   B   D   E     F   G   Gb   H   I   J   K   L   M   N   O     P   R   S     T   U   W   Y


Koko oro ti o bere pelu A

Lati Owo Phil Bartle

Ti a gbifo re lati owo Ade O'Dwyer, Toyin Olawale Jenyo


.

AGBARA LATI TESIWAJU:

Oro " agbara lati tesiwaju" je koko ninu eto iranlowo fun idagbasoke. ( a ko lee ri oro yii ninu opolopo iwe itumo - oro). O tumo si "agbara" ohun kan lati "tesiwaju" ( te siwaju sii) lehin ti a ba mu atileyin ara - ita kuro. Fun awon awujo ti o seto omi ero, atunse, fifo ati lilo ero ifa - omi lehin ti a ti ko tan, ni awon ohun ti a fe

Fun Olugbowosile lati ita, itesiwaju awon ise - agbese tabi aseyori ise - agbese lehin ti olugbowosile ba ti fiwon sile. Fun iwo ti o je olusekoriya, itesiwaju awujo, ifokunfun eto awujo lehin ti o ba ti fiwon sile. Fun olumojuto ayika ati awon ohun abemi, itesiwaju nilo ki ayika lee se atileyin fun asayan ise - sise, ti of i je wipe awon ohun elo ti a ko le sodotun ko ni tan.

العربيّةالاستمرارية,    Bahasa Indonesia: Keberlangsungan,    Català: sostenibilitat,    Deutsch: Nachhaltigkeit, die nachhaltigkeit,    Ελληνικά: Bιωσιμότητα,    English: sustainability,    Español: sostenimiento,    Filipino/Tagalog: maipapatuloy,    Français: durabilité,    Galego: sostentabilidade,    हिन्दी (Hindi): निरंतरता,    日本語: 継続,    Italiano: sostenibilita,    Kiswahili: udhibiti,    Română: dezvoltare durabila,    Português: sustentabilidade,    Pyccкий: устойчивость,    Af Soomaali: xejin,    Srpski: održavanje,    తెలుగు: ఉద్ధరణము,    ไทย: ความยั่งยืน,    Tiên Việt: Tạm dịch là sự phát triển bền vững,    Türkçe: sürdürülebilirlik,  اردو (Urdu): سسٹينيبِلٹ, سسٹينيبِلٹی",    中文 / Zhōngwén: 持续性


 

ALAILORI

Ko si Olori. Laarin awon egbe olukojo ati olode kekeeke, ipile oselu ko farahan to bee, idogba ni o wopo ju. Ni ibi ti ko si enikan ti a le pe ijoye tabi oba, awon onimo nipa eda eniyan ati asa re npe awon egbe bee ni alailori.

Ni awujo igbalode, a lee ri won fun igba die laarin egbe awon ore. Ninu awon awujo kekeeke ati awon ti ko i ti fi idimule daradara nikanni a ti lee ri eto oselu alailori.

 Català: acèfal,    Deutsch: azephal,    Ελληνικά: ακεφαλοσ,    English: acephalous,    Español: acéfalo,    Français: acéphale,    Galego: acéfalo,    हिन्दी : बेसिर,    Italiano: acefalo,    Kiswahili: acephalous,    日本語: 指導者の欠如,    Português: acéfalo,    Română: acefa,    Pyccкий: ацефальное,    Srpski: bezglavni,    Türkçe: başsız,    中文 : 没有领导者


 

AKITIYAN

Akitiyan bere nigba ti awon egbe, egbe afojusun re, ba se nkankan, yato si kiko eko nipa re lasan. Ona ikeeko ti o munadoko julo ni ikeeko ti o ni akitiyan ninu, nibiti awon olukopa yio ti ma keeko nipa ise sise. Ise re gegebi olusekoriya ni lati se iwuri ati idari akitiyan awujo.

O o ti se koriya awujo ti o ba ti ko won jo fun ipade tabi ti o ba seto igbimo ti ko ti i se nkankan. O ti se koriya fun won lehin ti o ba ti je ki won kun fun akitiyan nikan, ie tesiwaju.

 العربيّة: الفعل,    Català: acció,    Deutsch: aktion,    Ελληνικά: Δράση,    English: action,    Español: acción,    فارسی: عمل کنی,    Filipino: akysion,    Français: action,    Galego: acción,    हिन्दी : कार्य, कार्रवाई,    Italiano: azione    日本語: 行動, 行動,   Kiswahili: vitendo,    हिन्दी: कार्रवाई,    Português: acção,    Română: actiune,    Pyccкий: Действие,    Srpski: akcija,    తెలుగు: చర్య,    Türkçe: faaliyet,    Yoruba: akitiyan,    中文 : 行动


 

ASA (CULTURE)

 বাংলা : ংস্কৃতি,    Bahasa Indonesia: budaya,    Català: cultura,    Deutsch: kultur,    Ελληνικά: πολιτισμοσ,    English: culture,    Español: cultura,    Euskera: kultura,    Ewe: asa,    Filipino/Tagalog: kultura,    Français: culture,    Galego: cultura,    Italiano: cultura,    日本語: 文化,    Kiswahili: tamaduni,    Malay: budaya,    Português: cultura,    Română: cultura,    Af Soomaali: dhaqanka,    Srpski: kultura,    Tiên Việt: văn hoá,    Türkçe: kültür,    Yoruba: asa,    中文 (Zhōngwén): 人类文化 
 
––»«––
Ti o ba ri oro ti o nilo ijiroro nibiyi, jowo.
Ti o ba se adako ohunkohun lati ihin yi,
jowo fi oriyin fun eni (tabi awon) ti o koko se agbkale re
ki o si tun pada wa fi ori re so http://cec.vcn.bc.ca/cmp/index.htm
Aaye ayelujara yi ni a gbani alejo nipase awon Awujo Ayelujara Vancouver (VCN)

© Ofin odako 1967, 1987, 2007 Phil Bartle
Lati wo Lourdes Sada
──»«──
Atunko: 2015.09.22


 Eko nipa eda eniyan ati asa re